1 Tẹsalóníkà 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù kú fún wa kí a lè ba à gbé títí láéláé. Èyí yóò rí bẹ́ẹ̀ yálà a sùn tàbí a wà láàyè pẹ̀lú rẹ̀.

1 Tẹsalóníkà 5

1 Tẹsalóníkà 5:1-19