1 Tẹsalóníkà 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ẹ tu ara yín nínú, kí ẹ sì máa gba ara yín níyànjú pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.

1 Tẹsalóníkà 4

1 Tẹsalóníkà 4:16-18