1 Tẹsalóníkà 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A gbàgbọ́ pé, Jésù kú, ó sì tún jíǹde, pé Ọlọ́run yóò mú gbogbo àwọn tí ó ti sùn nínú rẹ̀ padà wá.

1 Tẹsalóníkà 4

1 Tẹsalóníkà 4:11-18