1 Tẹsalóníkà 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nitòótọ́, ẹ ní ìfẹ́ fún àwọn arákùnrin tí ó wà káàkiri Makidóníà. Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ àwa ń bẹ̀ yín, ará, pé kí ẹ̀yin kí ó máa tẹ̀síwájú nínú rẹ̀.

1 Tẹsalóníkà 4

1 Tẹsalóníkà 4:1-18