À ń gbàdúrà wí pé, kí ó wu Ọlọ́run pàápàá àti Olúwa wa Jésù Kírísítì láti rán wa padà sí ọ̀dọ̀ yín lẹ́ẹ̀kan sí í.