1 Tẹsalóníkà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A fẹ́ràn yín púpọ̀, èyí ló mu kí ó ṣe é ṣe fún wa láti pín ìyìnrere náà fún yín pẹ̀lú ìgbésí ayé àwa pàápàá.

1 Tẹsalóníkà 2

1 Tẹsalóníkà 2:1-12