A kò bèèrè ìyìn lọ́dọ̀ yín tàbí fún ara wa. Gẹ́gẹ́ bí àpósítélì Kírísítì a ò bá ti di àjàgà fún un yín.