1 Tẹsalóníkà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ọ̀rọ̀ ìyànjú wa kì í se ti ẹ̀tàn, tàbí ti èrò àìmọ́, tàbí láti inú àrékérekè.

1 Tẹsalóníkà 2

1 Tẹsalóníkà 2:1-8