1 Tẹsalóníkà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ń rántí lí àìsinmi nígbà gbogbo níwájú Ọlọ́run àti Bàbá iṣẹ́ ìgbàgbọ́yín, iṣẹ́ ìfẹ́ yín àti ìdúró sinsin ìretí yín nínú Jésù Kírísítì Olúwa wa.

1 Tẹsalóníkà 1

1 Tẹsalóníkà 1:1-5