1 Sámúẹ́lì 9:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì dìde ní àfẹ̀mọ́jú, ó pe Ṣọ́ọ̀lù sórí òrùlé pé, “Múra, èmi yóò rán ọ lọ.” Nígbà tí Ṣọ́ọ̀lù múra tán òun àti Sámúẹ́lì jọ jáde lọ síta.

1 Sámúẹ́lì 9

1 Sámúẹ́lì 9:22-27