1 Sámúẹ́lì 9:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù dáhùn pé, “Ṣùgbọ́n èmi kì í há à ṣe ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì? Kékeré nínú ẹ̀yá Ísírẹ́lì: Ìdílé mi kò há rẹ̀yìn jùlọ nínú gbogbo ẹyà Bẹ́ńjámínì? Èésì ti ṣe tí ìwọ sọ̀rọ̀ yìí sí mi?”

1 Sámúẹ́lì 9

1 Sámúẹ́lì 9:19-27