1 Sámúẹ́lì 9:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ó wà,” wọ́n dáhùn. “Ó ń bẹ níwájú u yín, múra nísinsìn yìí, ó ṣẹ̀ ṣẹ̀ wá sí ọ̀dọ̀ wa lónìí ni, nítorí àwọn ènìyàn ní ẹbọ rírú ni ibi gíga.

1 Sámúẹ́lì 9

1 Sámúẹ́lì 9:9-19