1 Sámúẹ́lì 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará Bẹ́ńjámínì kan wà, ẹni tí ó jẹ́ aláàánú ọlọ́rọ̀, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Kíṣì, ọmọ Ábíélì, ọmọ Sésórì, ọmọ Békórátì, ọmọ Áfíà ti Bẹ́ńjámínì.

1 Sámúẹ́lì 9

1 Sámúẹ́lì 9:1-5