1 Sámúẹ́lì 7:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yẹra fún Báálì àti Áṣitarótì, wọ́n sì sin Olúwa nìkan ṣoṣo.

1 Sámúẹ́lì 7

1 Sámúẹ́lì 7:1-8