1 Sámúẹ́lì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ọdún dé ọdún, ó lọ yíká láti Bẹ́tẹ́lì dé Gílígálì dé Mísípà, ó sì ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì ní gbogbo ibi wọ̀nyí.

1 Sámúẹ́lì 7

1 Sámúẹ́lì 7:8-17