1 Sámúẹ́lì 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mọ àwòrán àrùn oníkókó àti ti eku èlírí yin tí ó ń ba orílẹ̀ èdè náà jẹ́ kí o sì bu ọlá fún Ọlọ́run Ísírẹ́lì, Bóyá yóò gbé ọwọ́ rẹ̀ kúrò lára yín, lára ọlọ́run yín àti lára ilẹ̀ yín.

1 Sámúẹ́lì 6

1 Sámúẹ́lì 6:1-12