1 Sámúẹ́lì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọwọ́ Olúwa wúwo lára àwọn ènìyàn Ásídódù àti gbogbo agbègbè rẹ̀: ó mú ìparun wá sórí wọn, ó sì pọ́n wọn lójú pẹ̀lú àrùn oníkókó.

1 Sámúẹ́lì 5

1 Sámúẹ́lì 5:2-11