1 Sámúẹ́lì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìgbà tí àwọn Fílístínì ti gba àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run lọ, wọ́n gbé e láti Ebenésérì sí Ásídódù.

1 Sámúẹ́lì 5

1 Sámúẹ́lì 5:1-8