1 Sámúẹ́lì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa gbé! Ta ni yóò gbà wá kúrò lọ́wọ́ Ọlọ́run alágbára yìí? Àwọn ni Ọlọ́run tí ó fi ìpọ́njú pa àwọn ará Éjíbítì pẹ̀lú gbogbo àjàkálẹ̀-àrùn ní ihà.

1 Sámúẹ́lì 4

1 Sámúẹ́lì 4:6-11