1 Sámúẹ́lì 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó dárúkọ àpótí ẹ̀rí Olúwa, Élì sì ṣubú sẹ́yìn kúrò lórí àga ní ẹ̀gbẹ́ bodè, ọrùn rẹ̀ ṣẹ́, ó sì kú, nítorí tí ó jẹ́ arúgbó ọkùnrin, ó sì tóbi, ó ti darí àwọn Ísírẹ́lì fún ogójì ọdún.

1 Sámúẹ́lì 4

1 Sámúẹ́lì 4:16-22