1 Sámúẹ́lì 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin náà sọ fún Élì, “Mo ṣẹ̀ ṣẹ̀ dé láti ibi ogun náà ni: mo sá láti ibi ogun náà wá lónìí.”Élì sì béèrè pé, “Kí ni ó ṣẹlẹ̀ ọmọ mi?”

1 Sámúẹ́lì 4

1 Sámúẹ́lì 4:6-22