1 Sámúẹ́lì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élì gbọ́ ìró ohùn ẹkún náà ó sì béèrè pé, “Kí ni ìtúmọ̀ ariwo yìí?”Ọkùnrin náà sì sáré tọ Élì wá

1 Sámúẹ́lì 4

1 Sámúẹ́lì 4:6-19