1 Sámúẹ́lì 31:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìjà náà sì burú fún Ṣọ́ọ̀lù gidigidi, àwọn tafàtafà si ta á ní ọfà, o sì fi ara pa púpọ̀ lọ́wọ́ àwọn tafàtafà.

1 Sámúẹ́lì 31

1 Sámúẹ́lì 31:1-8