1 Sámúẹ́lì 31:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì kó egungun wọn, wọ́n sì sin wọ́n lábẹ́ igi kan ní Jábésì, wọ́n sì gba ààwẹ̀ ní ijọ́ méje.

1 Sámúẹ́lì 31

1 Sámúẹ́lì 31:4-13