1 Sámúẹ́lì 31:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì fi ìhámọ́ra rẹ̀ sí ilé Áṣítárótì: wọ́n sì kan òkú rẹ̀ mọ́ odi Bétísánì.

1 Sámúẹ́lì 31

1 Sámúẹ́lì 31:5-11