1 Sámúẹ́lì 31:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Fílístínì sì bá Ísírẹ́lì jà: àwọn ọkùnrin Ísírẹlì sì sá níwájú àwọn Fílístínì, àwọn tí ó fi ara pa sì ṣubú ní òkè Gílíbóà.

1 Sámúẹ́lì 31

1 Sámúẹ́lì 31:1-11