1 Sámúẹ́lì 30:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì kó àwọn aya Dáfídì méjèèjì nígbèkùn lọ, Áhínóámù ará Jésírẹ́lì àti Ábígáílì aya Nábálì ará Kámélì.

1 Sámúẹ́lì 30

1 Sámúẹ́lì 30:3-6