1 Sámúẹ́lì 30:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin sì wọ ìlú, sì wò ó, a ti kun ún ni iná; àti obìnrin wọn, àti ọmọkùnrin wọn àti ọmọbinrin wọn ni a kó ni ìgbèkùn lọ.

1 Sámúẹ́lì 30

1 Sámúẹ́lì 30:1-9