1 Sámúẹ́lì 30:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni yóò gbọ́ tiyín nínú ọran yìí? Ṣùgbọ́n bi ìpín ẹni tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ si ìjà ti rí, bẹ́ẹ̀ ni ìpín ẹni ti ó dúró ti ẹrù; wọn ó sì pín in bákan náà.”

1 Sámúẹ́lì 30

1 Sámúẹ́lì 30:22-31