1 Sámúẹ́lì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élì béèrè pé, “Kín ni ohun tí ó sọ fún ọ?” “Má ṣe fi pamọ́ fún mi. Kí Olúwa mi ṣe bẹ́ẹ̀ sí ọ àti jù bẹ́ẹ̀ lọ pẹ̀lú, bí ìwọ bá fi ohunkóhun tí ó wí fún ọ pamọ́ fún mi.”

1 Sámúẹ́lì 3

1 Sámúẹ́lì 3:13-21