1 Sámúẹ́lì 29:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Fílístínì sì kó gbogbo ogun wọn jọ sí Áfékì: Ísírẹ́lì sì dó ni ibi ìsun omi tí ó wà ní Jésírélì.

1 Sámúẹ́lì 29

1 Sámúẹ́lì 29:1-3