1 Sámúẹ́lì 28:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì búra fún un nípa Olúwa pé, “Bí Olúwa ti ń bẹ láàyè, ìyà kan kì yóò jẹ́ ọ́ nítorí nǹkan yìí.”

1 Sámúẹ́lì 28

1 Sámúẹ́lì 28:1-15