1 Sámúẹ́lì 27:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì wí ní ọkàn ara rẹ̀ pé, “Ǹjẹ́ ni ìjọ kan ni èmi yóò ti ọwọ́ Ṣọ́ọ̀lù ṣègbé, kò sì sí ohun tí ó yẹ mí jù kí èmi yára sá àsálà lọ sórí ilẹ̀ àwọn Fílístínì: yóò sú Ṣọ́ọ̀lù láti máa tún wa mi kiri ní gbogbo agbégbé Ísírẹ́lì: èmi a sì bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀.”

1 Sámúẹ́lì 27

1 Sámúẹ́lì 27:1-4