1 Sámúẹ́lì 26:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábíṣáì sì wí fún Dáfídì pé, “Ọlọ́run ti fi ọ̀ta rẹ lé ọ lọ́wọ́ lónìí: ǹjẹ́ èmi bẹ̀ ọ́, ṣáà jẹ́ kí èmi o fi ọ̀kọ̀ gún un mọ́lẹ̀ lẹ́ẹ̀kan, èmi kì yóò gun un lẹ́ẹ̀méjì.”

1 Sámúẹ́lì 26

1 Sámúẹ́lì 26:2-14