1 Sámúẹ́lì 26:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀jẹ̀ mi ó ṣàn sílẹ̀ níwájú Olúwa; nítorí ọba Ísírẹ́lì jáde láti wá ẹ̀mí mi bi ẹni ń dọdẹ àparò lórí òkè ńlá.”

1 Sámúẹ́lì 26

1 Sámúẹ́lì 26:18-24