1 Sámúẹ́lì 26:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì rékọjá sí ìhà kejì, ó sì dúró lórí òkè kan tí ó jìnnà réré; àlàfo kan sì wà láàrin méjì wọn:

1 Sámúẹ́lì 26

1 Sámúẹ́lì 26:4-19