1 Sámúẹ́lì 26:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa má jẹ́ kí èmi na ọwọ́ mi sí ẹni àmì òróró Olúwa: ǹjẹ́ èmi bẹ̀ ọ́, mú ọ̀kọ̀ náà tí ń bẹ níbi tìmùtìmù rẹ̀, àti ìgò omi kí a sì máa lọ.”

1 Sámúẹ́lì 26

1 Sámúẹ́lì 26:8-20