1 Sámúẹ́lì 25:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dìde, ó sì dojúbolẹ̀, ó sì wí pé, “Wò ó, jẹ́ kí ìránṣẹ́bìnrin rẹ ó jẹ́ ìránṣẹ́ kan láti máa wẹ ẹsẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ olúwa mi.”

1 Sámúẹ́lì 25

1 Sámúẹ́lì 25:31-44