1 Sámúẹ́lì 25:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì wí fún Ábígáílì pé, “Alábùkún fún ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, tí ó rán ọ lónìí yìí láti pàdé mi.

1 Sámúẹ́lì 25

1 Sámúẹ́lì 25:27-35