1 Sámúẹ́lì 25:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi bẹ̀ ọ́, fi ìrékọjá arábìnrin rẹ jìn ní: nítorí Olúwa yóò fi ìdí ìjọba olúwa mi múlẹ̀, nítorí pé ó ja ogun Olúwa. Nítorí náà kí a má ri ibi kan ni ọwọ́ rẹ níwọ̀n ìgbà tí ó wà láàyè.

1 Sámúẹ́lì 25

1 Sámúẹ́lì 25:22-35