1 Sámúẹ́lì 25:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Odi ni wọ́n sáà jásí fún wa lọ́sànán, àti lóru, ni gbogbo ọjọ́ ti a fi bá wọn gbé, tí a n bojútó àwọn àgùntàn.

1 Sámúẹ́lì 25

1 Sámúẹ́lì 25:10-18