1 Sámúẹ́lì 23:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì pe gbogbo àwọn ènìyàn náà jọ sí ogun, láti sọ̀kalẹ̀ lọ sí Kéílà, láti ká Dáfídì mọ́ àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 23

1 Sámúẹ́lì 23:1-12