1 Sámúẹ́lì 23:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì wí pé, “Alábùkún fún ni ẹ̀yin nípa Olúwa; nítorí pé ẹ̀yin ti káàánú fún mi.

1 Sámúẹ́lì 23

1 Sámúẹ́lì 23:17-23