1 Sámúẹ́lì 22:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Áhímélékì ọmọ Áhítúbì tí a ń pè ní Ábíátarì sì bọ́; ó sì sá àsálà tọ Dáfídì lọ.

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:15-23