1 Sámúẹ́lì 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí pé, “Áhímélékì, kíkú ni ìwọ yóò kú, ìwọ àti gbogbo ìdílé baba rẹ̀.”

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:10-19