1 Sámúẹ́lì 22:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì kúrò níbẹ̀, ó sì sá sí ihò Ádúlámù; nígbà tí àwọn arákùnrin rẹ̀ àti ìdílé baba rẹ̀ sì gbọ́, wọ́n sì sọ̀kalẹ̀ tọ̀ ọ́ wá níbẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:1-8