1 Sámúẹ́lì 20:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí o bá wí pé, ‘Ó dára náà,’ nígbà náà, ìránṣẹ́ rẹ wà láìléwu. Ṣùgbọ́n tí ó bá bínú gidigidi, ìwọ yóò mọ̀ dájú pé ó pinnu láti ṣe ìpalára mi.

1 Sámúẹ́lì 20

1 Sámúẹ́lì 20:2-10