1 Sámúẹ́lì 20:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì sì kọ sí ọmọdékùnrin náà pé, “Sáré! Yára! Má ṣe dúró!” Ọmọdékùnrin Jónátanì sì ṣa àwọn ọfà náà, ó sì tọ olúwa rẹ̀ wá.

1 Sámúẹ́lì 20

1 Sámúẹ́lì 20:35-41