1 Sámúẹ́lì 20:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì mú kí Dáfídì tún ìbúra ṣe nítorí ìfẹ́ tí ó ní síi, nítorí tí ó fẹ́ ẹ gẹ́gẹ́ bí ó ti fẹ́ràn ara rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 20

1 Sámúẹ́lì 20:15-18