1 Sámúẹ́lì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Ó gbé tálákà sókè láti inú erùpẹ̀ wá,ó gbé alágbe sókè láti orí òkítì eérú wá,láti mú wọn jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ-aládé,láti mu wọn jogún ìtẹ́ ogo:“Nítorí pé ọ̀wọ̀n ayé ti Olúwa ni,ó sì ti gbé ayé ka orí wọn